Intro
Yeah! Yeah!
Na wonder wonder we dey see, we dey see
Verse 1
Ifeto si omo bi se koko o
Ose ko
Oro ayeyi okan bobo o
Okan bobo
Emaje kafi iya to omo o
Kafi Iya to omo
Omo ti à o to lagbe ile ti a kò ta.
Lagbe ile ti a ko ta .
Iyawo mi oOh
Kato sere é é é
Jeka soro isititi funrawa
Shoma gbo
Omo tafe bi
Kamo iye omo tafe bi
Kamo Owo tafeni
Kamo iru ile tafe ko.
Chorus
Iyawo mi oni temíí…
Shoma gbo temi
Ma se banu je o
Koya gbo temi
Irin ajo laye je o
Oda kafi eto si (2x)
Outro
Oda kafi eto sí …
Kole dara….. ah
Funwa…..ah
Eni to ba fe rin Irin ajo
Sebi oni Lati mo iye toni Lati mudani
Oni Lati se eto Irin ajo na
Irin ajo ni igbeyewo ati loko laya je laye
Eje Kamo ohun tense o
Kade mo omo eni tanse .