Chorus
Oba ni e lowo,oba ni e kole oba ni ke bimo oo
Fetosomo bibi o se koko o se pataki.
Omo repete osi repete o di laelae o di gbere ee
Ori tonsise lo n jise taba fetosomobibi
Oba ni e lowo oba ni e kole oba ni ke bimo o o
Fetosomo bibi o se koko o se pataki
Omo repete osi repete o dilaelae o di gbere e e
Verse 1
Ori to n sise lo n jise taba feto somo bibi i i,
Fetosomo bibi ka le jare osi ka le jare ise ee
Beere ona ko ma sonu ko to sonu unuu,
Chorus
Oba ni e lowo,oba ni e kole oba ni ke bimo oo
Fetosomo bibi o se koko o se pataki.
Omo repete osin repete o di laelae o di gbere ee
Ori tonsise lo n jise taba fetosomobibi
Oba ni e lowo, oba ni e kole, oba ni ke bimo o o
Fetosomo bibi o se koko o se pataki2
Omo repete osi repete o di laelae o di gbere e e
Drama Skit/Bridge
Voice 1: Junio ki lo wa se ni ile?
Voice 2: Owo suku ni mo wa gba ma
Voice 1: So fun won pe o ba emi ati baba ni ile
Voice 2: N se wa lo so fun won pe n ba yin ni ile
Voice 1: O da joko sile ni igba yan
Voice 2: maa joko sile na o e je ki n joko ti awon egbon mi
Voice 3: Mumi junio o ki lo de ti e n da awon omo duro bayi ti e o je ki won lo si sukuu? Ee won ti bere esamu ni suku na! Eyin mo n ba wi!
Voice 1: Bukata awon omo yi naa ni
Voice 3: Melo le bi ti e n pe bukata awon omo yi naa ni? E bi ju merin lo ni?
Voice 1 : Mewa ni won o
Voice 3: Mewa ni won! Aa ! Olorun yoo ba yin wo won o
Voice 3: Ifetosomo bibi ti n lo ni asiko yi, o ti kuro ni won ni pe. Onikoro wa, onifisi wa…
Voice 1: O da emi naa a se o,
Voice 3: Mumi junio o e tete lo o
Chorus
Oba ni e lowo,oba ni e kole oba ni ke bimo oo
Fetosomo bibi o se koko o se pataki.
Omo repete osin repete o di laelae o di gbere ee
Ori tonsise lo n jise taba fetosomobibi
Oba ni e lowo oba ni e kole oba ni ke bimo o o
Fetosomo bibi o se koko o se pataki
Omo repete osi repete o dilaelae o di gbere e e